O ma se o! Otun Balogun tilu Ileefe ti jade laye

Lagbala iroyin la ti gbo pe Oloye Adegunju Adesakin to je Otun Balogun tilu Ileefe ti jade laye laaro yii.




Osu kewa odun yii lo ye ki Baba Adesakin pe omo odun merinlelogorin sugbon ti iku pa ojuu re de leyin aisan ranpe.


No comments:

Post a Comment