Oloye Mojisoluwa Akinfenwa ti ku o!

Alaga igbimo egbe oselu Alliance for Democracy lorileede yii, Oloye Mojisoluwa Akinfenwa ti jade laye.

Ilu Ibadan la gbo pe baba naa dake si leyin to lo nnkan aadorun odun laye.

Omobibi ilu Erin-Ijesa nijoba ibile Oriade ni baba naa.

No comments:

Post a Comment