Adeleke/Oyetola: Ile-ẹjọ ti mu ọjọ idajọ

Ile-ejo to n gbo esun to suyo leyin idibo gomina ipinle Osun to waye losu kesan odun to koja ti kede pe ojo fraide ose yii ni won yoo sedajo.




Leyin atotonu awon agbejoro ati alaye awon eleri olupejo, Seneto Ademola Adeleke ati olujejo, Alhaji Gboyega Oyetola, ni ile ejo fiwe sita laipe yii pe ojo fraide to n bo yii nidajo yoo waye lori eni to tọ sipo gomina ipinle Osun.

No comments:

Post a Comment