Lagbala iroyin la ti ri gbo pe wahala nla be sile lagbegbe Upper Igun Third East Circular Road, nilu Benin nipinle Edo nigba ti olopa ti okunrin kan senu tirela.
Olopa naa beere ogorun naira lowo okunrin toun ati afesona re ti won n mura igbeyawo jo wa ninu moto sugbon ti iyen so pe adota naira loun ni.
O sokale ninu moto lati salaye sugbon se ni olopa fibinu ti senu tirela to n sare bo, tirela si fo o lori yannayanna.
Kia lawon odo agbegbe naa lu olopa na pa, won si tun dana sun gbogbo awon moto ti won ba lago olopa lojo naa.
No comments:
Post a Comment