Alaga ajo eleto idibo ilẹ wa, Ojogbon Yaqub Mamood ti so pe ki awon egbe oselu bere ipolongo ibo won pada titi di alẹ ọjọ Tosde.
Latigba ti won ti sun idibo ojo satide to koja siwaju lawon egbe oselu ti n so pe ofin faaye sile fun awon lati bere ipolongo ibo pada niwon igba ti won ti fi ose kan kun idibo.
Laipe yii ni atejade kan wa lati ọdọ ajọ naa pe kawọn ẹgbẹ oselu bere ipolongo won pada.
No comments:
Post a Comment