Ooni Ogunwusi sọ aṣiri ori-itẹ fun Naomi, olori rẹ tuntun

Ooni ilẹ Ifẹ, Oba Enitan Babatunde Ogunwusi, Ojaja 11 ti sọ fun olori tuntun to ṣẹṣẹ fẹ bayii pe iberu Olorun nikan lo le mu un duro ni ipo nla naa.


Lasiko ti Ooni Ogunwusi n safihan olori re ohun, Shilekunola Moronke Naomi, eni to je omo ijo Seventh Day Adventist naa ni ori-ade yii ni ipo olori Ooni Ife je eyi to ni opolopo ofin ati eewo, eni to ba si ni iberu Olorun nikan lo le kogo ja nibẹ.

O waa ki Olori Moronke Naomi kaabo sinu igbeyawo alarinrin naa.

No comments:

Post a Comment