Lobatan! Ali Modu Sheriff pada sinu egbe oselu APC
Gbogbo eto lo ti to bayii lati gba alaga tele fegbe oselu PDP lorileede yii Seneto Ali Modu Sheriff sinu egbe oselu APC.
Loni layeye naa yoo waye nilu Abuja Abuja, ti awejewemu yoo si tele e nilu re nipinle Borno.
A oo ranti pe ile ejo to gajulo lorileede yii lo gba ipo alaga egbe PDP lowo Sheriff, to si gbe e fun Markafi lopin odun to koja.
A gbo pe latigba naa lo ti fi erongba re han lati pada sinu egbe APC to ti kuro lọdun 2015 nigba to so pe awon kan yan oun je ninu egbe naa.
Alaga apapo egbe APC, Odigie Oyegun pelu akowe funjoba apapo orileede yii toun naa wa lati ekun ibi ti Sheriff ti wa la gbo pe Aare Buhari yan lati gba Sheriff atawon eeyan re wonu egbe.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment